
Another hint Track from minister Afolabi olaide popularly knows as OlaideOmoObaOrun
After her last track Titled Fanu Gbemidebe,she press further dropping this newly updated track Titled “E’se Olore mi.
E’se Olore mi is a thanksgiving song for every individual in the body of Christ
E’se Olore is now available on all platforms
LYRICS
Ldv: E’se Olore mi
E’se Alanu mi
Fun iyanu ti mori gba Jesu emase
Chorus: E’se Olore mi
E’se Alanu mi o
Fun iyanu ti mori gba Jesu eku ise
Ldv: Fun iyanu re ti mori
Fun abo re lori mi
Opolopo lo ti ku
Ti won ti file saso bora
Morowore o, ninu aye mi o
Iyanu nla lo je,Jesu eku ise
(Back to chorus)
Fi’yin fun Jesu Olurapada wa
Ki aye ko kiki ife re nla
Fi’yin fun,eyin Angeli ologi
Fola, Atogo fun oruko re
Boluso Aguntan,Jesu yio to omo re
Lapa re lo n gbe won le lojojo
Eyin eniyan mimo
Tin gboke Sion
Fi’yin fun pelu orin Ayo.
Ldv: Alati leyin mi loje
Oluso Ayemi ni
Oko o ku momi lori
Mi o sokun lori omo
Morowore o ninu ise mi
Iyanu nla lo je
Jesu eku ise
Chorus: E’se Olore mi
E’se Alanu mi o
Fun iyanu ti mori gba Jesu eku ise.
(Sing till fade)!!!